Top Banner
Ohun gbogbo t o n lti mọ ̀ npa wọn abẹ ́ rẹ ́ jẹsra Covid-19: wọn ttọ ́ n knkn: wọn abẹ ́ rẹ ́ jẹsra ngba ̀ m l. wọn abẹ ́ rẹ ́ jẹsra Covid-19 ti kn oj ṣwọ ̀ n lwu t le jlọ. wọn abẹ ́ rẹ ́ jẹsra ndb bo gbogbo l rẹ. K s ẹ ̀ r p wọn abẹ ́ rẹ ́ jẹsra Covid-19 n ipa lr agbra bmọ. wọn akitiyan gby nl ni ti wọn abẹ ́ rẹ ́ jẹsra Covid-19 lẹ ́ yn. K s rj ara nyn tb ti ẹranko, tb ẹyin nn tkọ wọn rj wọn abẹ ́ rẹ ́ jẹsra Covid-19. wọn abẹ ́ rẹ ́ jẹsra w lti db bo wọ, wọn t o fẹ ́ rn ti wọn nyn t w n yk rẹ. Yoruba
3

Yoruba Àwọn abẹ́rẹ́ àjẹsára wà láti dáàbò bo ìwọ, àwọn tí ...

Oct 15, 2021

Download

Documents

dariahiddleston
Welcome message from author
This document is posted to help you gain knowledge. Please leave a comment to let me know what you think about it! Share it to your friends and learn new things together.
Transcript
Page 1: Yoruba Àwọn abẹ́rẹ́ àjẹsára wà láti dáàbò bo ìwọ, àwọn tí ...

Ohun gbogbo ti o ni lati mọ nipa awọn abẹrẹ ajẹsara Covid-19:

Awọn otitọ ni kankan:

Awọn abẹrẹ ajẹsara ngba ẹmi la.

Awọn abẹrẹ ajẹsara Covid-19 ti kun oju oṣuwọn ailewu ti o le julọ.

Awọn abẹrẹ ajẹsara ndaabo bo gbogbo ilu rẹ.

Ko si ẹri pe awọn abẹrẹ ajẹsara Covid-19 ni ipa lori agbara ibimọ.

Awọn akitiyan agbaye nla ni o ti awọn abẹrẹ ajẹsara Covid-19 lẹyin.

Ko si eroja ara eniyan tabi ti ẹranko, tabi ẹyin ninu atokọ awọn eroja awọn abẹrẹ ajẹsara Covid-19.

Awọn abẹrẹ ajẹsara wa lati daabo bo iwọ, awọn ti o fẹran ati awọn eniyan ti o wa ni ayika rẹ.

Yoruba

Page 2: Yoruba Àwọn abẹ́rẹ́ àjẹsára wà láti dáàbò bo ìwọ, àwọn tí ...

Ohun gbogbo ti o ni lati mọ nipa awọn abẹrẹ ajẹsara Covid-19:

! Gba awọn otitọ lati awọn orisun ti o ṣe e gbarale, ti o ṣe e fi ọkan tan.

! Ṣe agbekalẹ akojọpọ awọn orisun yẹn: awọn wẹbsaiti fun NHS, Ajọ Ilera Agbaye (WHO), ati Ẹgbẹ Alagbeelebuu Pupa Ilẹ Gẹẹsi (a jẹ ajọ kan ti ko fi si apakan ti a fi ara ji fun riro awọn eniyan lagbara pẹlu awọn otitọ).

! Lo akoko lati ka nipa ki o si loye awọn abẹrẹ ajẹsara Covid-19. Ti ohunkohun ba yẹ fun alekun ipele itọju ati agbeyẹwo, ilera rẹ ni o jẹ.

! Ti o ba ka nnkan kan lori awọn ojuko iroyin igbalode tabi ninu ijiroro ẹgbẹ ori WhatsApp kan ti ko da ọ loju, gbe igbesẹ kan pada sẹyin ki o si ṣe iwadii nipa rẹ funraarẹ.

! Awọn iṣe wa nni ipa lori awọn ẹlomiran, ni awọn ọna pataki.

Ranti:

Page 3: Yoruba Àwọn abẹ́rẹ́ àjẹsára wà láti dáàbò bo ìwọ, àwọn tí ...

Ohun gbogbo ti o ni lati mọ nipa awọn abẹrẹ ajẹsara Covid-19:

Awọn Abẹrẹ Ajẹsara: - O to miliọnu mẹta ẹmi ti awọn abẹrẹ ajẹsara

ngbala ni Ilẹ Gẹẹsi ati kari aye ni ọdọọdun.

- Nitori awọn abẹrẹ ajẹsara, awọn aisan bi ilẹẹgbona, rọpa-rọsẹ ati arun ipa ko si mọ tabi wọn ti ṣọwọn gidigidi.

- Ti a ba gba abẹrẹ ajẹsara, a tun ndaabo bo ẹnikan ti o ni ailera ju wa lọ, ti o le ma le gba abẹrẹ ajẹsara funraarẹ (fun apẹẹrẹ awọn ti ara wọn ko da tabi ti eto ajẹsara ara wọn mẹhẹ).

Ailewu abẹrẹ ajẹsara Covid-19: - Ko si bi wọn ti le fi ọwọ si awọn abẹrẹ

ajẹsara naa fun ọpọlọpọ miliọnu awọn eniyan ti iyemeji kankan ba wa nipa ailewu, pipeye tabi ṣiṣe iṣẹ rẹ.

- Awọn oṣuwọn yii ni a gbe kalẹ lati ọwọ Ajọ Ti O Nbojuto Awọn Oogun Ati Awọn Ohun Elo Itọju Ilera [Medicines and Healthcare products Regulatory] ti o nrii daju pe gbogbo oogun ti a nlo ni Ilẹ Gẹẹsi wa ni ailewu.

- Wọn dan abẹrẹ ajẹsara Oxford/AstraZeneca wo lara ẹgbẹrun mọkanla eniyan o le. Wọn dan abẹrẹ ajẹsara Pfizer/BioNTech wo lara ẹgbẹrun mẹtalelogoji ati abọ eniyan.

Awọn orisun

NHS – https://www.nhs.uk/conditions/coronavirus-covid-19/coronavirus-vaccination/coronavirus-vaccine/?gclid=EAIaIQobChMIybeg86O87QIVVOvtCh00OAFSEAAYASAAEgKs3PD_BwE Ajọ Ilera Agbaye (WHO) – https://www.who.int/emergencies/diseases/novel-coronavirus-2019/covid-19-vaccines UK – https://www.gov.uk/coronavirus Scotland – https://www.gov.scot/coronavirus-covid-19/ Wales – https://gov.wales/coronavirusNorthern Ireland – https://www.nidirect.gov.uk/campaigns/coronavirus-covid-19

Idagbasoke abẹrẹ ajẹsara Covid-19: - Ko si abala kankan ti a fo lara igbesẹ naa.

- Ohun mẹta ni o jẹ ki idagbasoke abẹrẹ ajẹsara ya kankan: owo nla, awọn alekun ohun elo, ati ọpọlọpọ awọn oniṣẹ iwadii. Igbesẹ dagbasoke abẹrẹ ajẹsara Covid-19 ni mẹtẹẹta.

- Ko si abẹrẹ ajẹsara miran ti o tii ni iru atilẹyin agbaye iru eyi ri.

- Afojusun kan ni agbaye ni – lati fi opin si itankalẹ kokoro arun apani yii – nitori naa awọn ijọba kaakiri agbaye ṣe agbekalẹ alekun owonaa.

Bi awọn abẹrẹ ajẹsara Covid-19 ti nṣiṣẹ: - Awọn abẹrẹ ajẹsara naa maa nṣiṣẹ nipa

fifi ami ranṣẹ si eto ajẹsara ara rẹ lati ṣẹda awọn olugbeja ti o nba kokoro arun naa ja.

- Wọn kii yi DNA rẹ pada.

- Ko si ẹri pe wọn nni ipa lori agbara ibimọ.

Awọn eroja abẹrẹ ajẹsara Covid-19: - Wọn o ni eroja ara eniyan kankan,

eroja ẹranko tabi ẹyin.

Iwoye kan ti o jinlẹ sii…