Top Banner
ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE ORO AJE ATI ETO ISUNA NI IPINLE ONDO
22

ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

Jan 26, 2020

Download

Documents

dariahiddleston
Welcome message from author
This document is posted to help you gain knowledge. Please leave a comment to let me know what you think about it! Share it to your friends and learn new things together.
Transcript
Page 1: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018

ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE ORO AJE ATI

ETO ISUNA NI IPINLE ONDO

Page 2: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

1

ITUMO AWON EDE TI A LO FUN IWE ETO ISUNA YI LEDE GEESI

BUDGET: Eyi je iwoye afojusun iye ti ijoba n petepero lati na ni saa kan tabi laarin

odun kan

Recurrent expenditure: Owo ti ijoba ya soto lati fi sanwo osu fun awon osise ijoba,

yiyanju ele lori gbese, owo ti o wa fun isakoso pelu iseto kalokabo awon ile ise ijoba

elekajeka

Capital expenditure: Eyi je owo ti ijoba n na lori ise idagbasoke, bii eto eko ise ilu bi

atunse awon ile iwe, ile iwosan, atunse popono ati beebee lo.

Roll over fund: owo ti a ko na ni odun to koja, ti a tun fi si eto isuna odun yii.

Personnel costs: Eyi je ara owo ti a ya soto fun gbigbo bukaata owo osu awon osise

ati awon ti o ti fehinti lenu ise ijoba

Budget support: Iye owo ti ijoba apapo fi se iranlowo tabi atileyin ijoba ipinle, fun

sisan owo osu ati owo ifeyinti fun awon osise ijoba ipinle lati ba kere koja ami

Overhead costs: O je owo ti ijoba fi n bojuto idojuko ti o ba de lojiji

Debt stock: Eyi ni apapo gbese ti ijoba je labele tabi seyin odi niwon saa kan

Debt Servicing: Eyi ni owo ti a ya soto ninu isuna fun yiyanju ele ori ojulowo gbese

abele ati tile okeere

Revenue: Apapo owo ti ijoba n pa wole laaarin saa kan

Consolidated revenue fund charge: Ara owo ti ijoba n lo fun sisan owo osu awon

oselu ti o dipo akoso mu, owo ifehinti ati owo osu osise fehinti, owo ajemonu fun

awon gomina ana ati awon igbakeji won.

Cash-backed capital expenditure: Eyi je owo ti o wa lowo fun amuse awon ojulowo

ise

Statutory allocation: Eyi ni ipin owo ti ipinle n gba lati odo ijoba apapo losoosu, eyi ti

ajo FAAC n se akoso pinpin re.

Utilised capital expenditure: Eyi ni apapo owo ise ti ile ise kookan, titi kan elekajeka

ile ise maa san sita fun ise ti awon kongilakito tabi elomiran ba se.

IPSAS: ifojusun alakale isuna ile ise ijoba jakejado agbaye (International Public

Sector Accounting Standards)

IMPPR: Alakale kari ile iseto isuna l’awon ile ise

JMPPR: Ipese ise labe akoso eto ogbin, iseto idokowo ati eka dida ile ise sile

Page 3: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

2

M- Mimu idagbasoke l’opo yanturu deba ipese awon ohun ko see mani pelu bi bojuto

won daradara

P- Ipese eko ti o muna doko ati imo gbogbonise fun idagbasoke

P- Ipese eto ilera ti o see yangan pelu wiwa ni arowoto

R- Idagbasoke igberiko

ALAKALE ISUNA 2018

- Alakale eto isuna alabode (MTEF) ati igbese sise n tele.

- Iwe isaju ipe ti o ko jade lojo kejo osu kejo, odun 2017

- Iwe ipe aseoba to jade lojo keta osu kokanla 2017

- Ipe saaju ipade alabesekele waye ni ojo kerindinlogun si ojo ikejidinlogun osu

kokanla, 2017

- Ipade igbimo alabesekele waye lati ojo kerin titi di ojo ikarundinlogun osu

kejila odun 2017

- Tite pepe iwe isuna sile asofin ipinle Ondo, ojo kejilelogun osu kejila, 2017

- Siso iwe isuna d’ofin, waye ni ojo ketadinlogbon osu kinni, 2018

- Ifowosi iwe isuna, waye ni ojo kefa osu keji, 2018

- Abojuto, isoduwon ati isagbeyewo eto isuna

- Sise agbeyewo ibi a ba ise de ni osu merin merin

BI OWO TI SE MAA WOLE: Owo ti ijoba n reti fun odun 2018 yii je bilionu

mokanlelogosan, irinwo le merinlelogun milionu, ojilelegbaametadinlogbon ati orin

lelugba ole meta naira, (N181,424,540,283.00)

A ONA AMUSE ISE:

i. Ipin lati odo ijoba apapo - N25, 352,256,000.00

ii. Owo apawole labele - 20,923,646,783.00

iii. Ipin Faati (VAT) - 12,000,000,000.00

iv. Anaku isuna odun ti o koja - 13,500,000,000.00

v. Owo lori alumoni - 5,536,592,000.00

vi. Ere lori iseto karakata sile okeere - 6,126,000,000.00

vii. Owo ti a gba pada lori ona ijoba apapo ti ijoba ipinle se atunse won

- 10,000,000,000.00

viii. Alekun owo gbese Paris Club - 13,156,000,000.00

ix. Alekun owo epo bentirolu - 3,683,000,000.00

x. Owo iranlowo - 6,279,046,084.00

Aropo gbogbogbo - 126,556,540,867.00

Page 4: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

3

B EYAWO:

i. Owo atileyin eto isuna - 10,925,000.000.00

ii. Eyawo alabode/abele - 31,194,564,633.00

iii. Eyawo lati odo awon ajo onidagbasoke ti

ile okeere - 12,748,434,783.00

Akojopo - 54,867,999,416.00

Aropo A + B - 181,424,540,283.00

Bi owo ti se maa wole ni isori isori f’odun 2018

Apapo isuna je : N181, 424,540,283.00

Page 5: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

4

Ibi ti owo le gbawole yato si yiya

Apapo iye ti isuan iba je ti a ko ba yawo Kankan ni N126, 556,540,867.00

Apapo owoya: N54, 867,999,416.00

ATILEYIN ISUNA , 10,925,000,000.00

ISETO EYAWO LABALE,

31,194,564,633.00

ATILEYIN LODO AJO MAJEO BAJE,

12,748,434,783.00

Nibo ni awon owo yiya ti a fe lo ti maa jeyo?

Page 6: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

5

Independent Revenue: Je aropo iye ti a pa wole labele ni ipinle yii ti awon onigeesi n

pe ni “IGR”

Value Added Tax (VAT): Ni owo ori ti ijoba n gba lori iseto idunadura karakata nile

Naigiria.

19,000,000,000.00

15,398,700,000.00 14,764,363,121.11

20,923,646,783.00

2015 2016 2017 2018

Nai

raOWO APAWOLE LABELE

10,000,000,000.00

8,600,000,000.00

12,000,000,000.00 12,000,000,000.00

2015 2016 2017 2018

IPIN OWO FAATI

Page 7: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

6

Exchange Gain: Ere ti a je lori igbokegbode oja pasiparo naira si dollar. Ko si iru

anfani owo bee saaju odun2017

Eya Owo ti ijoba ya soto fun eto ise idagbasoke

Wo oju ewe kinni fun ekun rere alaye lori isori yii.

-

7,305,000,000.00

6,126,000,000.00

2016 2017 2018

Nai

raERE ORI PASIPARO (State)

23,000,000,000.00

39,755,000,000.00

55,697,216,878.89 54,867,999,416.00

2015 2016 2017 2018

Nai

ra

EYAWO

5,000,000,000.00

14,967,000,000.00

6,200,000,000.00

13,500,000,000.00

2015 2016 2017 2018

OWO ISUNA ANAKU

Page 8: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

7

Owo ori ajo ile ise, ti n wa epo pentirolu nile Naigiria. Ko si anfani owo yi saaju odun

2017

Owo ti oye ki ijoba apapo da pada lori atunse popona ti ipinle Ondo se.

Wo oju ewe kinnin fun ekunrere alaye.

6,644,000,000.00

3,683,000,000.00

2016 2017 2018

Nai

raOWO ORI ALEKU PENTIROLU

1,000,000,000.00

6,060,000,000.00

10,000,000,000.00

2015 2016 2017 2018

Nai

ra

OWO TI IJOBA IPINLE ONDO NA SORI POPONA IJOBA APAPO

68,000,000,000.00

41,000,000,000.00 44,020,000,000.00

40,888,848,000.00

2015 2016 2017 2018

Nai

ra

IPIN TIWA NINU OWO TI IJOBA APAPO N PIN FUN AWON IPINLE LATI OWO AJO FAAC

Page 9: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

8

Sisan alekun gbese ti a n san pada lori paris club bere lati odun 2017.

Owo iranlowo ti a mo si granti kii se owo asanpada. Ebun niru owo bee je fun ijoba lati dawole akanse ise.

13,156,000,000.00 13,156,000,000.00

2015 2016 2017 2018

Nai

raIDAPADA ALEKUN OWO GBESE TI A SAN LORI EYAWO PARIS

CLUB

4,000,000,000.00

5,000,000,000.00

6,279,046,084.00

2015 2016 2017 2018

Nai

ra

OWO IRANLOWO ILE OKEERE ATI LABELE

Page 10: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

9

NIBO NI A FE NA OWO TI A N RI YI LE LORI?

Page 11: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

10

ISUNA NI ISORI-ISORI

Owo isuna ti a n reti ni 2018 ni a ya soto fun:

i. Sisan ojulowo gbese pada (Principal) - N13, 599,878,084.00

ii. Ipin ni Isori: OSOPADEC - 6,214,636,800.00 10% IGR to JAAC Account - 2,093,364,678.30 Aropo gbogbogbo - 8,308,001,478.30

iii. Owo isakoso eto ise ijoba - 78,587,675,486.07 iv. Owo ti a fe fi sise - 80,928,985,234.00

Eto isuna 2018 ti a fowosi yii je eyi ti owo ti ijoba maa pa wole kere si eyi ti o ma na

lo (Deficit Budget).

OJU OWO LORI SISAN GBESE PADA,

13,599,878,084.63

ISETO INAWO IGBADE GBA,

78,587,675,486.07

IPIN TI A N DA PADA, 8,308,001,478.30

INAWO LORI AKANSE ISE,

80,928,985,234.00

BAWO LATI SE FE NA OWO WONYI?

Page 12: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

11

OWO IRANLOWO TI IJOBA N GBA

LATI ITA N 1,768,000,000.00

Kini nina re maa da le lori?

N793M

Ipese omi ero

N725M

Fun Awon Eto Eu Ati Unicef

I.E Abere ajesara HIV/AIDS

N150M

Pipese ebun eko ofe fun awon

omo bibi ipinle Ondo

N100M

Fun itoju awon igbooba ati ibojuto igi

gbingbin

Page 13: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

12

N 1.29B

Igbega ati atunse awon ile iwe

alakobere

N2.6B

Ipese ounje fun omo ile iwe

N50M

Ebun eko ofe fun awon akeko ni

pinle Ondo

N600M

Owo atilehin fun awon lajolajo

OWO IRANLOWO LABELE N 4,511,046,084.00

Kini a maa na owo naa le lori?

Page 14: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

13

OWO IRANLOWO LATI ODO AWON LAJOLAJO

N12, 748,434,783

NIBO NI OWO BEE NLO

N 1,768,000,000.00

N480M

Iseto ise iranra eniilowo

N3.050B

Ipese omi-ero

N3.0B

Atunse awon ona igberiko

N762.8M

Ironilagbara awon odo wa leka eto

ogbin

N900M

Eto ogbin FADAMA III project

N3.56B

Ipese ojulowo eto ilera jakejado

N1.0B

Abojuto ayika wa ati isele agbara omiyale

Page 15: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

14

Ate inawo ijoba lori sisan owo osu awon osise ati owo ajemonu miiran.

Inawo igbadegba lori gbigbo bukata ise ati eto ijoba, kii se pe won n san taara

f’awon osise ijoba. Apere owo bee ni: Owo rira petirolu, diesel, owo ina eletiriki, owo

oko lati ibi kan lo ibo miiran abbl.

37,705,000,000.00 37,000,000,000.00

51,004,000,000.00

37,909,962,000.00

2015 2016 2017 2018

Nai

raIYE- OWOTI IJOBA FI N IBOJUTO AWON OSISE

3,916,100,000.00 3,730,963,000.00 3,975,985,000.00

4,489,289,500.00

2015 2016 2017 2018

Nai

ra

OWO ISAKOSO ETO ISE IJOBA

Page 16: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

15

Awon akanse eto kii saba n waye bee losoosu, eekookan lo maa n waye. Apere ni

inawo lori sise olugbowo ere idaraya, ipese atileyin eto fawon obinrin, gbigbaradi sile

fun isuna olodoodun pelu awon eto miiran.

Owo giranti (grant) kii se eyi ti a n san pada. O je owo fun gbigbo bukata ise ati eto

ijoba. Apeere bee ni: owo iranlowo fun awon ile iwe giga ati abbl.

8,071,100,000.00

6,889,000,000.00

7,699,000,000.00

7,227,169,686.07

2015 2016 2017 2018

Nai

ra

ATILEYIN OWO FUN AWON EKA TABI AJO ILE ISE IJOBA

14,387,626,000.00 13,964,362,000.00

16,997,334,300.00 16,311,254,300.00

2015 2016 2017 2018

Nai

raAWON AKANSE ETO

Page 17: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

16

Eyi ni owo ti ijoba n pese fun ile ise iwe iroyin Owena Press.

Wo oju ewe kinni fun alaye

Eyi ni owo ti ofin gbe leyin lati maa fun awon ajo to da duro funra won bii: Ajo

OSOPADEC, ajo ti o n bojuto awon ijoba ibile abbl.

200,000,000.00220,000,000.00

180,000,000.00 150,000,000.00

2015 2016 2017 2018

Nai

raOWO GIRANTI ATI EYAWO

12,423,124,000.00

7,390,000,000.00

15,302,880,700.00 12,500,000,000.00

2015 2016 2017 2018

Nai

ra

CONSOLIDATED REVENUE FUND CHARGES

0

8,374,000,000.00 8,308,001,478.30

2017 2018

Nai

ra

Statutory Tranfers

Page 18: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

17

Akiyesi: A ti faye sile fun sisan ele ori igbese wonyi lati ara owo ti a fii nsan owo osu

awon oselu ti o dipo akoso ijoba mu, owo ifehinti ati owo ajemonu fun awon gonina

ana ati awon igbakeji won.

Inawo lori awon akanse ise je ara isuna lori ipin olodindi, lori ile ati lori awon dukia

miiran. O je owo ti ijoba n na lori awon ise bii kiko ile iwe, ipese ile iwosan, atunse

popona, ipese ohun elo leto abo abbl.

0

8,126,698,115.26

13,599,878,084.63

2017 2018

Nai

raSisan oju owo gbese (principal)

54,297,050,000.00 54,526,375,000.00

59,186,681,884.74

80,928,985,234.00

2015 2016 2017 2018

Nai

ra

owo ti ijoba n na awon ojulowo ise ati dukia

Page 19: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

18

Owo isuna fun ise akanse ise ni 2018 je N80,928,985,234.00

Ipin IPSAS ni owo iyasoto fun awon eto ise idagbasoke

131,000,000,000.00 123,720,700,000.00

170,846,580,000.00181,424,540,283.00

2015 2016 2017 2018

Nai

raAropo eto isuna odun 2015 wo 2018

Iseto ise lawon ofiisi

Abojuto eto oro ajeLAW AND JUSTICE, 1,457,000,000.00

Iseto igbayegbadun

Ipin owo IPSAS si isori isori

Page 20: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

19

Awon ise kookan ti a ya soto fun sise ni ipinle yii

N4.427B

Ipese omi ero

N3.2B

Sise atunse awon

ona

N9.583B

Ipin fun ajo UBEC ati

SUBEB

N670M

Eto gbogunti ise

asela

N2.0B

Agbekale ojuko itoju

arun jejere

N14.781B

Lila ati titun awon

ona se

N1.5B

Eto otun titun

N539M

Iseto ibudoko oju

omi

N4.202B

Ipese ounje ti n sara

lore fawon ile iwe

kookan ti a ya soto

N460M

Eto ise idagbasoke

igberiko

N1.635B

Iseto owo ise aje

ati igbeleke eto

idokowo

N662.5M

Gbingbin ojele

million meta koko

(cocoa)

N400M

Ina oni 33 KVA double circuit

power point

N1.2B

Owo ipin tiwa lori eto

akanse ise ti lajolajo

gbe owo kale fun

N900M

eto ogbin FADAMA

III

N4.0B

Kiko ibugbe tuntun

fun gomina ati

igbakeji re

Page 21: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

20

Awon ise ti a fe seto eyawo okeere fun labele.

Awon eto ti a fe eyawo abele se.

150,000,000.00

725,000,000.00 793,000,000.00

100,000,000.00

SCHOLARSHIP AWARDS EU & UNICEF PROGRAMMES

PROVISION OF POTABLE WATER

FOREST PRESERVATION & REGENERATION

Nai

ra

Awon ise ti a fe gba eyawo le lori lati ile okeere

Page 22: ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN …ondobudget.org/materials/ONDO STATE BUDGET YORUBA.pdfETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018 ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE

21

Pinpin isuna odun yii si isori marun ni ibamu si alakale ajo eleto isuna lagbaye.

Apapo isuna odun 2018: N181,424,540,283.00

Ipese isuna da lori alakale ijoba

Aropo awon eto miiran N12,429,489,000.00

ISETO ISE LAWON OFIISI,

34,820,296,722.10

ISETO ORI AJE, 73,882,940,997.55

OFIN ATI ETO IDAJO, 3,635,475,242.82

ETO IGBAYAGBADUN, 62,871,190,520.53

ISETO ELEKUNJEKUN, 6,214,636,800.00

IPESE ISUNA ODUN 2018 LABE ISORI ISORI

Job Creation through Agriculture,

Entrepreneurship and Industrialization, 9,215,785,000.00

Massive Infrastructural Development and

Maintenance, 26,193,160,000.00 Provision of Functional

Education and Technological …

Provision of Accessible and Qualitative Health Care and Socio Service

Delivery, 13,504,964,866.00

Rural Development and Community Extension

Services, 5,413,000,000.00

BUDGET ALLOCATION BASED ON JMPPR