Top Banner
.' (Jona lse akada ni ede Yoruba) University of Lagos Noriba 13 Odun 2007
8

ede Yoruba) .' University of Lagos

Oct 29, 2021

Download

Documents

dariahiddleston
Welcome message from author
This document is posted to help you gain knowledge. Please leave a comment to let me know what you think about it! Share it to your friends and learn new things together.
Transcript
Page 1: ede Yoruba) .' University of Lagos

.'(Jona lse akada ni ede Yoruba)

University of Lagos

Noriba 13

Odun 2007

Page 2: ede Yoruba) .' University of Lagos

~~~ 6nIcQwe inti N¢nba yii

ABiQoUN. Michael"tria i~ArPpOorilkp ninu Ede Yoruba: akiyesl lati inu~1

A.JiB6YE. OIadiip9O&a alayemaye lciaariin faweli otohun aarin ati ir6 ohun~ nimi Apoia Onibaatan lede Yoruba

ALABA, OIijgooyegaBa1ani ohlin ninu oruko onlsilebu meta l'ede Yoruba

~GB~oeleEm ciwUjQ nipa obinrin g~g$ bi 6 ti se han ninu iwe~ -em&ife_ a.J. • .

ASi'WAJU JumOke- . _.Minan ipOQkunrin ninu ewi obinrin

Ot..UIIUYM.4, Temitc?p~~ aJaye J6ri awon atoka iba-isele ninu awon eka(:de Ekiti

iv

JU WIiiiiiv

1 - 5

6 -17

18 - 24

25 - 39

40 - 58

59 - 67

Page 3: ede Yoruba) .' University of Lagos

OFIN ALA YEMAYE LAAARliN FAwELi OLOHUN MRiN AT!iRO OHON isAL~ NiNU ApoLA oNiaMTAN LEDE YOROsA

QLADliPQ [email protected]

Department of Linguistics, Afican & Asian StudiesUniversity of Lagos

Akoka-Yaba

iFAARA

Ariyanjiyan t6 n 10I¢w¢ ni boya faw$li olohun aarin t6 maa nwaye laaarin oro-oruko ini ati oro-oruko olohun ninu apolaonibaatan lede Yoruba, apeere iru eyi t6 wa ni (1) ni i?$ kan gunm¢t6 n se (wo Ajib6ye 2004,2005, Awobuluyi 2004).

(1 ) BadeT¢na

a.b.

Ohun ti i$$ yii maa dale kii ?e ariyanjiyan boya atoka ibatan walede Yoruba tab! k6 si. Awon i$$ wa nile t6 fi $ri t6 joju han peYoruba ni atoka lbatan ti irisi r$ j$ mora olohun aarin (M,uOA) niihun ipile (Ajib6ye 2005, 2007) .. $ugb¢n ti a n pe jade g$g$ bifaweli olohun aarin (FOA). Ni ihun oke yii, irisi re rnaa n j$ okan-unp$lu faw$1i t6 ba tele ninu apola oruko ini. Dip6 b$$, ilakaka wanibi ni lati se alaye aierno-fonoto]! ati ajemo-siritaasl 16ri ohun t6 n$~I$ si ir6 ohun isale ninu apola onibaatan naa. Akiyes] wa ni pe arnaa Ii diqba pa ir6 ohun isale t6 pekun apola ini je niqba ti a ko ba

.pe faweli olohun aarin t6 duro g$g$ bi atoka ibatan je.

(2) ¢g$d~¢g$d~

Dup$Dup$

a.b.

Ti a ba wo apeere (2a), a 6 ri rno pe ohun lsale ni 6 pari oro-orukoini, atoka ibatan ti irisl r$ j$ [~] si t$le. Ni (2b), a se akiyesi wi peirisi ofo ni atoka ibatan ni, suqbon ohun kan $~I$ si w6r6 faw$li t6

- 6 -

k'~yin oro-oruko ini. Ohun naa ni pe dip6 iro ohun lsale t6 ba way!tele, iro ohun aarin ni 6 mu jade. Bi ¢r¢ til$ ri bayii, eyi ko fa iyatritu~¢laaarin (2a) ati (2b) rara.

Akiyesi wa yii ni a tun f$ 16 g$g$ bi eri miiran lati fi $egbEleyin ero wa pe atoka ibatan yii wa ninu apola onibaatan ledEYoruba. Bi 6 til$ j$ pe igbes$/ayipada fonoloji ni eyi, sibe, 6 natubotan slntaasi.'

. Awon ohun ti 6 je awa loqun runu apileko yii ni lati wE.ldahun si awon ibeere wonyi eyi ti awon ise ti a rnenuba wonyi kcrnenuba: (a) $e kiki pe oro-oruko ini pari pelu faweli olohun aarint6 fun alaye abi a gb¢d¢ w6 tayo faweli t6 pekun oro-oruko ini kiohun lsale t6 di pipaje? (b) Se bi a ti le pa ir6 ohun lsale t6 bapekun oro-oruko ini j~ naa ni a le pa o~U~.6~e j~ t~ ~a. p$ku~ ,a~~I~oro-oruko ini? (d). $e lpaje ohun isale yll nI se pelu ihun sintaasiabi k6 ni nkan se pelu re?

Yato si pe ilakaka lati dahun ibeere wcnyi rnaa seqbe leyinise t6 ti w~ nile saaju, ohun rnarun-un patak: ni ldahun si alaye yiimaa se. Ekini, 6 rnaa fun wa ni oore-ofe lati se ~gbekal$ orisirisiapeere ti k6 si ninu awon i$$ i$aaju ti a rnenuba. Ekeji, a se afihanpe 'ki ir6 ohun lsale t6 Ie di pipaje ni sakani ti a f$ y$w6, gbogbofaweli t6 ba suyo ninu apola oro-oruko ini ni 6 gb¢d¢ ni ir6 ohunisal~ 16ri. Eketa ise yii maa fi han pe kik] iqba ti apola olohun bat$le'ap6Ia ini' ni ip~j~ ohun isale rnaa Ii waye. Ekerin, t? j$. ol~b?rini pe fifi ir6 ohun aarin dip6 ire ohun isale ti a paje ko wa lasan,ami atoka ibatan ni.2 Ekarun-un, i$$ yii rnaa j$ ki a nrno wi pe ornoiya ka~ naa ni ijeyo fa~$1i olohun aarin ati ipaje ohun lsale.

jPAJ; OHON jSAL~: ~Ri FONQLQJi

1 Wayi 0, a f~ yan f$r$ wi pe awa k9 ni eni a~9~Q. I~ n:aa. $~ akiy~~i yii: L~r~awon ise t6 Ii fenu kan an pe a maa n pa ir6 ohun lsale 10 pa pekun oro-oruko In!je ~i B~mgb6~e (1967, 1990) ati Dechatne (2001). AWQn i$$ mliran 16 tunrnenuba ihun onibaatan ni Ow61abi (1976. 1986).

2 Am¢ sa, boya 6 $ee$e ki ohun ti a n SQ nibi ~ip.ada ~i a ?a fi. $~Q ajEi!~Q-f6~$tiik.iwo ak6k6 Ii a fi pe wore faw$li olohun aarln to n ?I$~ al?ka ~b~~an. kl. ~ ~I.fi .w~pipe ihun naa nibi u a Ii ~a ir6 ohun isa.l$. I? pari, ¢.r?-~~k? "". !~.l~lo tru ~k9bee maa fihim b6ya ibi ti a ti pa ir6 ohun isale JEi!kuru JUIbl II a ko ti pa J~.

. . - 7 -

Page 4: ede Yoruba) .' University of Lagos

!, G$g$ bi iside fun i~$ lsori yii, e j$ ki a ?8 akiyesi awon

apeere to wa ni (3)-(7).

(3) a. a~a a Dup$b. a~a Dup$

(4).

a. ~wu u Badeb. ~wu Bade

(5) a. in) u klnltnmb. iru klnlhun

(6) a. igo 0 biab. igo bia

(7) a. apo o. ti wab. apo ti wa (f.w. Barnqbose 1990)

Awon apeere (3)-(7) ~ee pin si rneji: awon ti faweli olohunaarin ti jE;3YOg$9$ bi 6 ti han ni ¢w¢ (a) ati a ijE;3YO'r$ g$g$ bi 6 ti han~i ¢w¢ (b). Koko miiran ti a f$ fa jade 16ri ¢w¢ apeere t6 wa ni (b) nitl lro ohun aarin ti a fi dipo iro ohun isale tl a paje 16ri faweli t6keyin oro-oruko ini. .

Alaye ¢w¢ apeere to wa ni (b) 16ku ti a fe se bayii. Niw6n bi6 ti j$ pe sakan: ti a ti pa iro ohun isale jE;3ni ~yf ti gbogbo f~welioro-oruko ini ni lro ohun isale 16ri, a dabaa pe iro ohun isale k~npere ni awon faweli wonyl ni ni ihun ipile (f.w. Leben 1973 ati ~woni$$ rnliran). Ninu i$$ Ajiboye (2005), a ti fidi re mule pe at6ka .lbatan ni mora ,u.3 K6 ni ju abuda ohun aarin 10ni i"hun ipil$. .

(8) a p 0 ATOKA isATANg g g

J1 J1 + J1

<:: g

A

3 Ninu apileko yii, 1=ohun isale, A= ohun aarin, 0= ohun eke- 8 -

.Wayi 0, iqba tl a pa iro ohun isale or! faweli t6 pekun oro-oruko inij~, ohun to seku ni mora meji, faw$1i [0] ti k6 ni ir6 ohun, rnora ti k6ni iris! kan pate ati iro ohun aarln ti mora atoka ibatan ni lati ihunipile. .

(9) ag

J1gI

o ATQKAiBATAN

J1~J1gg

o A

p

Ohun t6 $E;3I$leyin eyi ni pe mora faweli t6 pekun oro-oruko lnl diplpaje, faw$1i re si so rno mora J1 t6 duro fun at6ka ibatan. Seakiyesi pe mora yii ti ni lro ohun tire latl ihun lpile. ir6 ohun naa ni ape jade 16ri faweli to pekun faweli oro-oruko ini naa.

(10) ag

J1gI

o ATQKAiBATAN

0~J1g

go A

p

Ohun t6 ku t6 j~ wa 16gun bayif ni alaye 16ri idi ti a fi maa ri pa ohunisale t6 keyin ¢r¢ -oruko ini jE;3.Ni ipari, a se Mihan idi re tl a kii fi rfatoka ibatan ni sakani ti a ba ti pa ohun lsale t6 keyin ninu apolaini j~.

Akiyes! Dechaine's (2001) ni wi pe ofin wofun ni 6 de tpa]eiro ohun isale nigba ti oro-oruko olohun ba bere p$lu konsonaritl. Tia k6 ba si ti pa ohun isale ti a n sore ba yii je, dandan ni ki a peworohun faweli ti 6 ri sise atoka ibatan yii, bi b$$ k¢ arnujade re koni j$ ipede Yoruba. .

(11) a.b.d.

iluilu u*ilu

batabatabata

Wayi 0, Dechaine tesiwaju pe saaju oro-oruko ol6hun to b$r$ p$lufaweli, dandan ni ki a pa iro ohun isale j~ niwon bi faweli t6 bereoro-oruko olohun ko ba tl ni lro ohun isale 16ri (12).

- 9 -

Page 5: ede Yoruba) .' University of Lagos

.••......

"

I

" iI

a. pataki ~mu b. okc;i 0 KunleI b. "pataki ~mu d. onilu u Kunle

/ d. "pataki ~mu (f.w. Dechaine 2001: 102) e. alapata a Kunle

Ohun milran ti Decnaine tun rnenuba ni pe a kii pa iro ohun isale jE?nlnu iru apeere t6 wa ni (13a) bee ni worohun 016~un .a~rin. kii suyoninu iru apeere t6 wa nl, (13b). Ninu iru apeere wonyr. 0 di dandanki ohun isale ori oro-oruko ini jeyo lori gbogbo faweli inu re, (13d).

Ni (16), niqba ti a fi tipatipa pa iro ohun isa'l$ ori awon oro-orukonaa j~, amujade ti a rl k6 si ninu ede Yoruba.

(13) a.b.d.

*ilu*ilu uill!

c;igac;igaQga

(16) a. "pako Kunle *O-Ab. *OkO Kunle *A-Ad. *onilu Kunle *A-O-Ae. "alapata Kunle *A-O-A-A

Niwon bi ko ti see se ki a pa lro ohun lsale j~ ni apeere t6 wa ni(16), ohun tl eyi n fi ye wa ni pe ki i se igbakugba t6 ba wu wa ni ale pa iro ohun lsale yii j~.

6 ku ohun kan ti a gb¢d¢ y$w6 ka tile gba pe 6 seese ki apa ir6 ohun orl faweli t6 keyin oro-oruko ini j~ nibi t6 ba ye: 6 YE?kia w6 6 boya bi oro-oruko lni se gun t6 ni se pelu lpaje ir6 ohunlsale ti a n sore ba, ApE?~rE?ti 6 wa ni (16-18) ni a fi se awari eyi. Nipate, ni (17), sllebu rneji ni oro-oruko lni, ni (18) sllebu meta ni ¢r¢-oruko ini ibe, Nl (19), sllebu rnerin ni oro-oruko ini t6 wa nibe. Sibe,g$g$ bi arnujade awon apeere wonyi ti fihan, ipa]e ir6 onun lsalekuku waye ninu gbogbo won.

86 tiI$ j$ wi pe awon akiyesl Oechaine yii t¢~a ni.bi ~U??, .afik9n. t~ ~f$ se ni pe ¢rc) ju ka so pe a k6 gb¢d¢ pa iro ?hun Isal~ J~ ~tnU .Ir~awon apeere wonyen. A gb¢dc) Ie so ohun. to ~e..ato~u~ fun. p.lpetabi aipe r$. Ni ti apeere (13a), afalrno ko ma JE?p~. apa~Q ofinfonetliki ati ti fonolo]] ti a me si 'aiigb6d6-si-iyat6' Ira ohun (NoHiatus) ni 6 rnu kl 6 sore lati pa ir6 ohun isale kan je ti ir6 ohunisale rneji ba wa lori silebu oni w6r6 faweli ni aala c)rc).Ni ti ap~~r~(13b) ohun ti Akinlabi ati Liberman (2000) ati Ajib6ye (2005) fi y~wa ni pe lpede wonyen t6 j$ atole fawelll meta ni aala ¢rc) ?ee gbawole ti asafo ba ri rora sore. . .

. Ohun kan tf a fe ki e se akiyesi ni pe gbogbo awon QrQ-oruko lni ti a yew6 wonyi ni 'pe ohun lsale 16 wa 16ri gbogbo faw$l~inu won. Bayii, e j$ ki a wo awon apeere t6 j$ pe kiki faweli t6 panoro-oruko ini ni 6 ni lro ohun isale.

"

(17) a. a~a ab. a~a

(18) a. c;ig~d~b. Qg~d~

(19) a. agb3agbab. agbaagba

(14) a. pak6 0-1b. okc;i A-Id. onilu A-O-Ie. alapata A-O-A-I

Nigba ti iru awon oro-oruko t6 wa rii (~4) ba .wQ.n~ ~hu~ o~i?a~t~ng$g$ bi oruko lni, ko see se ki a pa Ira ohun isale to keyln QrQ-oruko ini naa j~, (15).

KunleKunle

~ KunleKunle

a BeyioseBeyiose

Ohun t! eyl tun fi ye wa ni pe bi oro-oruko ini ti gun t6 tabi kuru t6ko ni se pelu ipaje ohun isale.

(15) a. pak6 Kunleo

- 10 - - 11 -

Page 6: ede Yoruba) .' University of Lagos

iPAJE OHUN isALE: ERi SINTAAsi. . . ~.

Ohun ti 6 kan ni ki a wo lpaje ohun isal$ ni sakani slritaasi.Ni atele aba Oechame (1993,1997,2001), a qba pe g$g$ bi ipajeohunisale ori 9r9 ise ti j$ alotee sintaasl (21), b$$ naa ni lpajeohun isale on oro-oruko inl j$.

(21) a.b.

Ade ta6 r~

isu >Ade >

Ade ta6 r~

Ti a ba fi ohun ti a ri ninu apeere (25) isale, eyi to se deede petuohun ti a ti n w6 bo we ohun to han nf (24), a 6 ri ijora ati iyat¢gedegbe laaarin won. E; k¢k¢ se akiyesi ohun ijora t6 wa ninuawon apeere 9w¢ mejeeji: konsonanti ni 6 bere eyan ni (24),kcnsonanf ni 6 bere oro-oruko olohun ni (25). $ugb¢n niqba ti a dair6 ohun ti ori oro-oruko ini si ni (24), ni (25) a pa ir6 ohun isale j~,a si fi ohun aarin dipo re nitori pe oro-oruko olohun ni 6 tele.

(22) a.b.

Ade beru Cj6891a soro ~bun

>>

*Ade beru Cj6. "Bola sore ~bun

-.(25) Ap6fa in! + Ap6fa Of6hun

Arnuwole Amujadea. a~a f.1 Kunle asa Kunleb. ~wu f.1 Tunde ewu Tunded. lru f.1 Bunrni iru Bunrnie. ig6 p T¢la igo Tela~. ap6 p. Bade apo Bade

Ohun ti Decnaine (2001) fi ye wa ni pe kiki igba ti oro lse onisilebukan t6 ni ir6 ohun isale lori ba gba oro-oruko sari-an g$g$ bi abo niohun isal$ naa le di plpale.

~w$, ti ab¢ ba j$ arcpo oruko g$g$ bi apeere, a ko Ie pa lro ohunisale naa j~.

(23) a.b.

Ade na6 r~

mimi

>>

"Ade na*0 re

mimi

Ka ni 6 ?ee se ki eyikeyii ¢r¢ eyan pa isori r$ da lati eyan (26a) sloro-oruko (26b) nigba naa, ipaje ir6 ohun isale le waye. Ohun ti a rini (26b) ni pe a S9 dudu di ¢r¢ oruko eniyan, lyen ni pe a Ie ri ipedenaa g$g$ bi 'ig6 ti enikan ti a ri pe ni Dudu'.

Fun $kunr$r$ alay~"ati awon $ri rniiran, wo i?$ Decbaine ti a tokasi.

Ni ti apola onibaatan ti a ti n w6 bo. ohun ti a ti fihan ni pe a. Ie pa ir6 ohun lsale j~ ninu apola oro-oruko ini bi apola oro-oruko

olohun ba tete. Sakani kan ti a ti f$ fi han pe eri stnritaasi wa funplpaje ohunisale ni ibi ti ¢r¢ eyan lasan ba ti tele 9r¢-.oru~c;>~ni di~6orooruko olohun. G$g$ bi amujade apeere (24) ti fihan, rpaje ohunisale ori oro-oruko (t6 Ie sise in i) ko waye o.

(26) ab.

ig6 duduigo Dudu

= dudu j$ eyan= dudu j$ oro-oruko"

Eyi gan-an ni a pe ru er! siritaasl. Ti 6 ba j$ ni ti Fon¢l¢ji ni,lrorisonati 16dijo bere won. $ugb¢n ti 6 ba j$ ti Sintasi, isori ¢t9(:>t9ni won: isor! ¢r¢ oruko yato si isori ¢r¢ eyan.

Ni ipari a f$ fi ye wa wi pe kii ?e kiki oro-oruko ini ninu apotaoruko nj a ti le pa iro ohun isale j~. G$g$ bi apeere, ti oro-oruko iniba gba eyan ti apola oro-oruko olohun ba tele, ti 6 je pe kiki iroohun isale 16 wa lori faw$1i re g$g$ bi 6 ti wa ni (27), a se akiyesi

(24) APOR + L;yana. a~a burukub. ~wu funfund. lru gigune. ig6 kekere

"asa buruku*~wu funfun"iru gigun*igo kekere

4 Wo Aw6buluyi (2004) fun awon alaye rniiran 16rieyi.

- 12 - - 13 -

Page 7: ede Yoruba) .' University of Lagos

Ipe 6fin to pa ire ohun lsale j~ lori faweli to pekun oro-oruko ini(iyen eyan) ~i~$ sibe (28). .(27) a. [Ap6 gudugb~ ~ Kunle] jabo

b. [lgba aim9 on wa] ni Olorun foju fo dad. [Ak9 palaba a Gbada] sonu

(28) a.b.d.

[Ap6 gudugb ~ Kunle] jabQ[lgba airno wa] ni Oiorun fojutoda[Ak9 palaba Gbada] sonu

Bayii, a ti se akanrnole re pe lpaje iro ohun lsale to rnaa Iiwaye ninu ihun onibaatan j$ ami ifibatan han lede Yoruba. Nibi tieyi ba ti waye. a rnaa Ii fi iro ohun aarin dipo ohun lsale ti a paje,t;ri kan patakl to ~egbe leyln i~$ Iwadli Dechaine (2001) to SQ peaj~p9 wa laaarin fonolo]] ati sintaasi Iede Yoruba to b$$ to j$ peti a ba ni lrno klkun nipa okan, 0 Ie ~e iranl¢w¢ funni atirno ohun toIi~~I$ ninu ekeji ni a tun ri nibi. Ohun ti a ri fayo ni pe bi 6 til$ j$ peipaj~ ire ohun isale ~i a Ii sore re yii j~ rno slntaasi, sibe ofinfon(>l(>ji ni 6 Ii tele. ldi ni pe igbes$ fonolojl ponnbele ni ipa]e,~gb(>n ihun smtaasl ni 0 se ona atiwaye re nitori kiki inu ihunonibaatan ti oro-oruko olohun ba t$le ni 0 ti Ie waye. Ohun ti 0 kanti a f$ fi han ni lsorl to keyln ni pe orne lya kan naa ni ipa]e iro ohuni5al$ ati wore faweli olohun aarin.

OFIN iFONKA ALAisEVATO NJFAwELI OLOHUN AARIN (FOA)All ipAJ"e iRO OHUN isAL$' .

Ohun kan to ku tl a f$ se alaye re ni ajosepo to wa laaarinij~Y9 mora olohun aarin ati ipaje iro ohun isale to pekun faweli inuapela oruko ini. Aba wa ni pe fifi ohun aarin tl awon onirno kan peni "diqerewu" (default) dipo ohun lsale tl a paje j$ okan-un pelufaweli olohun aarin tl 0 rnaa Ii wa ni aarin oro-oruko in! ati oro-oruko olohun, Ni pataki a f$ se Mihan re wi pe kiki iqba ti a ko bape atoka ibatan ti irisi re j$ faw$1i olohun aarfn ni ihun ipile ~i a toIe pa iro ohun isale to wa ni pekun faweli oro-oruko ini j~. Of in tode ohun ti a f$ se alaye re nibi ni 6 wa ni (29).

- 14 -

(29) a. Ti a ba pe f3W$1i olohun aarin, ko si ipaje iro ohunisaleTi a ko ba pe faweli olohun aarin, ipaje lro ohun lsa!egb¢d¢ waye .

b.

$,aaj~, ~ j$.ki, a koko se afihan awon ap~~r~ (30)-(32) t6 fi ye wa penlgbakugba ti a ba pe mora j1 olohun aarln, ipaje ir6 ohun isale kote waye. .(30) a. asa a Kunle

b. "asa a Kunle

(3.1 ) a. 99~d~ ~ Kunleb. *99~d~ ~ Kunle

(32) a. agbaagba a Beyioseb. *agbaagba a Beyiose

A tun f$ fi apeere to wa ni (33)-(35) $egbe I$yin ofin keji t6 SQpe ti~ ko ba pe faw$1i olohun aarin, ipaj~ ir6 ohun isal$ gb¢d¢ waye.AWQn ipede ti ko beti mu ti a fihan ni awon apeere (b) j$ ibi ti a ko tipe fawefi olohun aarln, ti a si tun k¢ lati pa iro ohun isale to keyinoro-oruko ini j~.

(33) a. a$a Kunleb. *a$a Kunle

(34) a. 99~d~ Kunleb. *99~d~ Kunle

(35) a. agbaagba Beyioseb. *agbaagba Beyiose

f; wa $e akiyesi pe ipaje lro ohun isale ko gunle iye silebu ti 0 waninu ap6/a oro-oruko ini. Ni (33), sllebu meji ni. Ni (34), silebumeta ni. Wayi 0, ni (35), silebu rnerin ni. Sibe bakan ni ofin naa sesise. ...-

- 15 -

Page 8: ede Yoruba) .' University of Lagos

I; j~ ka sare ran yin leti Ibeere meta ti a gbe ka iwaju wa latise alaye ipaj~ ire ohun isal$ ni sakani lhun onibaatan f)i lbere~pil~kQ yii, Ekini ni lati we boya kiki igba ti oro-oruko ini ba pari~ ohiln isal~nlkan ni a t6 Ie pa ir6 o.hun lsale .naa j~ tabi agbQdQ taYQ faw~1i t6 pekun oro-oruko inl. Ekeji ni lati we b6y~ a Iepa ire ohlin oke Ie ninu apola ini bi a ti Ie ~e pa ohun lsale j~. Eketani Jati fidi r$ mul$ pe iru apola t6 ba t$le oro-oruko ini (apola oro-oniko oI6hun tabi apola $yan) ~e pataki ni plpa ohun lsale t6 wafOri iaw~i to pekun apola oro-oruko ini je. Ohun ti abo iwadll wafihan ni pe ki ohun isale t6 Ie di plpaje, gbogbo faw$1i oro-oruko initabi ~yan ti ¢r(H?rUk9 ini qba gb¢d¢ ni ir6 ohun lsale lor! pata.Belkan naa ni a tun se akanrnole r$ pe nigba ti faw$1i oro-oruko initabi ~yan ti ¢rQ-orUk9ini gba ba pari p$lu faweil olohun eke, a ko Iepa ohlin 6ke y~n j~ latl fi sarni si ihun onlbaatan, Ni lparl a ti fidi r$~ pe lse QmQiya kan naa ni faw$1i olohun aarin ati lpaje ir6ohiIn isill~ ninu ihun onlbaatan: eyi 10fa a t6 fi j$ pe ibi ti a ba ti riQkan.a ki iri ikeji. Eyi ni a pe ni lfonka alaiseyato.

- 1 () -

AWQN iWE iTQKASi

Ajib6ye, Oladitpo. 2004. The syntax of Yoruba genitiveconstruction. 35th Annual Conference of African Linguistics.Harvard University, Boston.

Ajiboye, Oladiipo. 2005. Topics on Yoruba nominal expressions.Doctoral dissertation. University of British Columbia,Vancouver

Ajib6ye, QladiipQ. 2007. I~$ Mora Olohun Aarin (MpOA) inu Ap61aOnibaatan: ~rf laf inu ede agbaye. Pepa Apileko ti a ka nibiapero olodoodun f;gb$ Onirno Ede Yoruba. 2nd_6thOctober,

. 2007. Oyo State College of Education, Oyo.Akinlabi. Akinbiyi and Mark Libennan. 2000. The tonal phonology

of Yoruba clitics. In B. Gerlach and J. Grijnenhout, eds.Glities in Phonology, Morphology and Syntax. Amsterdam:John Benjamins.

Awobuluy], Oladele. 2004. On the so-called Genitive Morpheme inStandard Yoruba, read at the 24th WACL, University ofIbadan, Nigeria. August 1-6.

Barnqbose. AyQ. 1967. A Short Yoruba Grammar. London:Cambridge University Press.

Barnqbose, AyQ. 1990. Fonc;ik;ip eti Gireme Yorube. Ibadan:University Press.

Dechaine, Rose-Marie. 1993. Predicates across categories:Towards a category-neutral syntax. Doctoral D'ssertatior:..University of Massachusetts, Amherst.

Dechaine, Rose-Marie. 1997. On the left edge of Yorubacomplements. Paper presented at the University of Ibadanseminar series.

Dechaine, Rose-Marie. 2001. On the left edge of Yorubacomplements. Lingua111: 81-130.

Leben, W. 1973. Suprasegmental phonology. New York. Garland.Ow61abi, D.K.O. 1976. Noun-Noun Constructions in Yoruba: A

Sytactic Analysis. PhD Thesis. University of Ibadan.Owolabi, D.K.O. 1986. Gerundive Nominals in Yoruba. 1ih WALe.

University of Ibadan.

- 17 -